Agbeyewo Akoonu Awon Tiori Fonoloji ni Ede Yoruba

dc.contributor.authorRABIU, Ridwan Akinkunmi
dc.contributor.authorBALOGUN, Nasrudeen Akanbi
dc.date.accessioned2024-11-25T12:36:17Z
dc.date.available2024-11-25T12:36:17Z
dc.date.issued2022-06
dc.descriptionThis work indigenized and nativized selected phonological theories in Yoruba language.
dc.description.abstractIṣe ̣́ ìwádìí yìí ṣe àlàyé le ̣́kùn-ún lórí àkóónú tío ̣́rí fono ̣́lo ̣́jì me ̣́ta ní èdè Yorùbá. Àwọn tío ̣́rì náà ni tío ̣́rì Onídàrọ (Generative Phonology), tío ̣́rì Adápelení (Auto-segmental Phonology) àti tío ̣́rì Olùborí akópa (Optimality theory). Àfojúsùn iṣe ̣́ ìwádìí yìí ni láti ṣàlàyé àwọn tío ̣́rì yií ní èdè Yorùbá, èyí tí yóó túbo ̣̀ je ̣́ kó rọrùn si fún àwọn ake ̣́ko ̣̀o ̣́ èdè Yorùbá tí wọn nílò àwọn tío ̣́rì yìí fún ìtúpale ̣̀, pàápàá jùlọ nínú iṣe ̣́ àkànṣe wọn. Èyí ríbe ̣́e ̣̀ níwo ̣̀n ìgbà tó je ̣́ pé bàtà ò sí òde ò yá ni tío ̣́rì je ̣́ fún iṣe ̣́ ìwádìí ajẹmédè. Iṣe ̣́ ìwádìí yìí gùnlé iṣe ̣́ àwọn onímo ̣̀ ìsáájú bí i Chomsky ati Halle (1968), Goldsmith (1978), Prince àti Smolensky (1991) abbl. Díe ̣̀ lára ohun tí a rí fàyọ nínú iṣe ̣́ ìwádìí yìí ni pé àlàyé lórí àwọn òfin fono ̣́lo ̣́jì tí ó ń ṣiṣe ̣́ afárá láàárín ìhun ìpìle ̣̀ àti ìhun òkè afo ̣̀ ni tío ̣́rì onídàrọ fúnka mọ. Bákan náà àlàyé lórí òmìnira àmì ohùn ge ̣́ge ̣́ bí ègé tí ó lè dádúró láì fi ti ègé ìró ṣe ni kókó ohun tí tío ̣́rì adápelení fúnka mo ̣́. Àlàyé wa lórí tío ̣́rì olúborí akópa fìdí re ̣̀ múle ̣̀ pé agbára òté (constraint) àti òǹfà ìsopo ̣̀ (Evaluator) lórí síṣe ̣̀dá afo ̣̀ aṣeégbà ni kókó èrò tío ̣́rì adápelení. Ní ìkádìí, a rọ àwọn onímo ̣̀ èdè láti tubo ̣̀ tẹpẹlẹ mo ̣́ títú àwọn tío ̣́rì ajẹmédè palẹ̣̀ sí èdè Yorùbá láti mú kí kíko ̣́ èdè Yorùbá pe ̣̀lú ìtúpale ̣̀ àwọn èròjà àmúkale ̣̀ fáye ̣̀wò pe ̣̀lú àwọn tío ̣́rì fonolo ̣́jì yìí rọrùn fún àwọn olùko ̣́ àti ake ̣́ko ̣̀o ̣́ èdè Yorùbá.
dc.description.sponsorshipSelf
dc.identifier.citationNIL
dc.identifier.issnNIL
dc.identifier.urihttps://kwasuspace.kwasu.edu.ng/handle/123456789/2826
dc.language.isoother
dc.publisherYORÙBÁ: Journal of Yorùbá Studies Association of Nigeria
dc.relation.ispartofseries11; 2
dc.titleAgbeyewo Akoonu Awon Tiori Fonoloji ni Ede Yoruba
dc.typeArticle
Files
Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
AGBEYEWOAKOONUAWONTIORIFONOLOJINIEDEYORUBA.pdf
Size:
403.17 KB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed to upon submission
Description: