ATUNGBEYEWO IGBESE IYOPO FAWELI NINU EDE YORUBA ERI LATI INU ORUKO AJEMO IBI ATI ENI

dc.contributor.authorRidwan Akinkunmi RABIU
dc.date.accessioned2024-11-25T12:31:25Z
dc.date.available2024-11-25T12:31:25Z
dc.date.issued2021
dc.descriptionThis research work examine the status of vowel coalescence as a phonological process in Yoruba language using evidence from Yoruba name-data which involve Yoruba place and personal names.
dc.description.abstractIse iwadii yii fi oju otun wo iyopo faweli gege bi igbese fonoloji ninu ede Yoruba. Erongba ise iwadii yii ni lati lo eri lati inu awon oruko ajemo ibi ati oruko ajemo eni fi idi ijeyo iyopo faweli pelu ona ti o n gba waye ninu ede Yoruba mule. Ona meji ni a gba sakojo awon eroja amukale fayewo wa: lati inu ise awon onimo isaaju ati igbasile awon wunren oro lati odo awon abena imo wa. Tiori onidaro eyi ti Chomsky ati Halle (1968) ṣe agbateru re. Koko ohun ti a ri fayo ninu ise iwadii yii ni pe iyopo faweli wa gege bi okan lara igbese fonoloji inu ede Yoruba, ti ijeyo resi fi oju hande ninu iseda awon oruko ajemo ibi bi i “Akeetan ati Ogbomoso”. Ijeyo iyopo faweli tun fi oju han ninu iseda awon oruko ajemo eni bi i “Adenuga”, “Awonuga”, “Oyenusi”, Omoruyi abbl. Ni ikadii, a ro awon asewadii ninu imo eda-ede lati tubo tepele mo fifi imo fonoloji ati awon eka imo-eda-ede toku bi i mofoloji, sintaasi, semantiiki abbl. se itupale awon oruko Yoruba nitori opo ohun ti o farasin ninu ede ni iru ise iwadii bee le tu sita.
dc.description.sponsorshipSelf
dc.identifier.citationNIL
dc.identifier.issnNIL
dc.identifier.urihttps://kwasuspace.kwasu.edu.ng/handle/123456789/2817
dc.language.isoother
dc.publisherIlorin Journal of Linguistics, Literature and Culture
dc.relation.ispartofseries9; NIL
dc.titleATUNGBEYEWO IGBESE IYOPO FAWELI NINU EDE YORUBA ERI LATI INU ORUKO AJEMO IBI ATI ENI
dc.typeArticle
Files
Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
ATUNGBEYEWO IGBESE IYOPO FAWELI NINU EDE YORUBA ERI LATI INU ORUKO AJEMO IBI ATI ENI.pdf
Size:
569.27 KB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed to upon submission
Description: