Òrò-Îse Kú nínú Ìkíni Yoruba
dc.contributor.author | Tella Samson Adekunle | |
dc.date.accessioned | 2025-07-16T09:11:35Z | |
dc.date.available | 2025-07-16T09:11:35Z | |
dc.date.issued | 2021-06-30 | |
dc.description | Nil | |
dc.description.abstract | Oríṣìíríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe ló wà ní èdè Yorùbá. Àbùdá, ibi ijẹyọ, ìlò àti ìtumọ̀ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì wà lọ́wọ́ sàkáání tí wọ́n ti jẹ yọ. Nínú iṣẹ́ yìí, a ó wo èrò àwọn onímọ̀ nípa ọ̀rọ̀-ìṣe kú bí ó ti jẹ yọ nínú ìkíni Yorùbá, a ó sì se àwílé tiwa kí á tó se ìgbéléwọ̀n ọ̀rọ̀-ìṣe yìí. A sàkíyèsí pé ojúlówó ọ̀rọ̀-ìṣe ni kú pẹ̀lú àbùdá àdámọ́ ibi ìjẹyọ tó sàrà ọ̀tọ̀. A tún sàkíyèsí pé àkọpọ ọ̀rọ̀-arọ́pọ̀ orúkọ ẹnìkejì ẹyọ ẹ àti ọ̀rọ̀-ìṣe kú kìí se ẹkú ní ìbámu pẹ̀lú èrò Awobuluyi (2013). A tún sàkíyèsí ní ìbámu pẹ̀lú èrò àwọn onímọ́ pé ẹ̀dà ọ̀rọ̀-ìṣe kú ni ọ̀rọ̀-ìṣe kí nítorí pé ibi tí kí ti jẹ yọ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, kú kò lè jẹ yọ̀. Ìdí nìyí tí àwa fi pè kú ní Ọ̀rọ̀-ìṣe Onítumọ̀-Àkànlò kí. Kókó Ọ̀rọ̀: Ọ̀rọ̀-Ìṣe, Ìkíni Yorùbá, Ọ̀rọ̀-arOríṣìíríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe ló wà ní èdè Yorùbá. Àbùdá, ibi ijẹyọ, ìlò àti ìtumọ̀ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì wà lọ́wọ́ sàkáání tí wọ́n ti jẹ yọ. Nínú iṣẹ́ yìí, a ó wo èrò àwọn onímọ̀ nípa ọ̀rọ̀-ìṣe kú bí ó ti jẹ yọ nínú ìkíni Yorùbá, a ó sì se àwílé tiwa kí á tó se ìgbéléwọ̀n ọ̀rọ̀-ìṣe yìí. A sàkíyèsí pé ojúlówó ọ̀rọ̀-ìṣe ni kú pẹ̀lú àbùdá àdámọ́ ibi ìjẹyọ tó sàrà ọ̀tọ̀. A tún sàkíyèsí pé àkọpọ ọ̀rọ̀-arọ́pọ̀ orúkọ ẹnìkejì ẹyọ ẹ àti ọ̀rọ̀-ìṣe kú kìí se ẹkú ní ìbámu pẹ̀lú èrò Awobuluyi (2013). A tún sàkíyèsí ní ìbámu pẹ̀lú èrò àwọn onímọ́ pé ẹ̀dà ọ̀rọ̀-ìṣe kú ni ọ̀rọ̀-ìṣe kí nítorí pé ibi tí kí ti jẹ yọ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, kú kò lè jẹ yọ̀. Ìdí nìyí tí àwa fi pè kú ní Ọ̀rọ̀-ìṣe Onítumọ̀-Àkànlò kí. Kókó Ọ̀rọ̀: Ọ̀rọ̀-Ìṣe, Ìkíni Yorùbá, Ọ̀rọ̀-ar | |
dc.description.sponsorship | Self | |
dc.identifier.citation | Tella Samson Adekunle, Òrò-Îse Kú nínú Ìkíni Yoruba | |
dc.identifier.uri | https://kwasuspace.kwasu.edu.ng/handle/123456789/5685 | |
dc.language.iso | other | |
dc.publisher | Yoruba Studies Association of Nigeria | |
dc.relation.ispartofseries | 10; 4 | |
dc.title | Òrò-Îse Kú nínú Ìkíni Yoruba | |
dc.title.alternative | Nil | |
dc.type | Article |