ATUNGBEYEWO ORO-ASOPO GEGE BI ISORI ORO NINU EDE YORUBA

dc.contributor.authorRidwan Akinkunmi RABIU
dc.date.accessioned2024-11-25T12:58:25Z
dc.date.available2024-11-25T12:58:25Z
dc.date.issued2021-06
dc.descriptionThis research work examine the status of conjunction as a lexical category or functional category in Yoruba language using phonological, morphological as well as syntactic features that distinguish conjunction as word class in the language as yardstick.
dc.description.abstractKoko ohun ti a gbeyewo ninu ise iwadii yii ni atungbeyewo awuyewuye ti o n suyo lori oro-asopo gege bi isori oro ninu ede Yoruba. Orisun awuyewuye yii ni aiko enu awon onimo girama ede Yoruba lori iye isori oro to wa ninu ede naa. A se igbelewon ise yii pelu ero awon onimo isaaju lori ipo ti oro-asopo wa ninu ede Yoruba, se isori oro ni tabi ise lasan? Ogbon iwadii ti a lo nii se pelu agbeyewo awon ise awon omoran lori iye isori oro to wa ninu ede Yoruba. Ise iwadii yii fidi re mule pe isori oro ponbele ni oro-asopo ninu ede Yoruba tako ero awon onimo ni i Yusuf (1999), Ajiboye (2011) ati Asekeye (2002, 2012 ati 2016) PE isori ise lasan ni oro-asopo ninu ede Yoruba. Lara awon abuda ti a ri fayo ninu ise iwadii yii ti o gbe ero wa lese pe isori-oro ni oro-asopo ni pe abuda fonoloji re fihan pe ami ohun isale ni o maa n bere gbogbo oro-asopo to wa ninu ede Yoruba. Abuda mofoloji oro-asopo ti o ya a soto si awon isori oro to ku ni pe mofiimu ipile ni gbogbo oro-asopo ti o wa ninu ede Yoruba. Ni ti abala sintaasi, agbedemeji ihun ti a fe sopo yala o je eyo Oro, apola tabi odidi gbolohun ni oro-asopo maa n wa. Ni ikadii, ero wa ni pe ise iwadii yii ti yanju awuyewuye ti o wa lori okan ninu awon isori oro to wa ninu ede Yoruba eyi tii se oro-asopo.
dc.description.sponsorshipSelf
dc.identifier.citationNIL
dc.identifier.issnDOI: 10.13140/RG.2.2.15346.58563
dc.identifier.urihttps://kwasuspace.kwasu.edu.ng/handle/123456789/2837
dc.language.isoother
dc.publisherYORÙBÁ: Journal of Yorùbá Studies Association of Nigeria
dc.relation.ispartofseries10; 4
dc.titleATUNGBEYEWO ORO-ASOPO GEGE BI ISORI ORO NINU EDE YORUBA
dc.typeArticle
Files
Original bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
ATUNGBEYEWOOROASOPO.pdf
Size:
503.56 KB
Format:
Adobe Portable Document Format
Description:
License bundle
Now showing 1 - 1 of 1
Loading...
Thumbnail Image
Name:
license.txt
Size:
1.71 KB
Format:
Item-specific license agreed to upon submission
Description: