Browsing by Author "Hakeem Olawale"
Now showing 1 - 4 of 4
Results Per Page
Sort Options
- ItemÀgbéyẹ̀wò Ìlò-Èdè Nínú Orin Ìbílẹ̀ Ìlọrin(2021) Hakeem OlawaleỌ̀kan pàtàkì tí kò ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn lára ẹ̀ka tí lítíréṣọ̀ alohùn Yorùbá pín sí ni orin jẹ́. Bárakú sì ní ọ̀rọ̀ orin láwùjọ ọmọ ènìyàn pàápàá jù lọ àwọn Yorùbá nítorí pé onírúurú ààyè ni orin ti máa ń jẹ jáde nínú ìgbésí-ayé wọn lójoojúmọ́. Bí àwọn akọrin àwùjọ bá sì ń ṣiṣẹ́ ọnà wọn, ìjìnlẹ̀ èdè tó jinná ni wọ́ n fi máa ń gbé e jáde tí yóò sì máa ṣàfihàn bí irú àwọn akọrin bẹ́ ẹ̀ ṣe gbọ́ èdè àti ìmọ̀ nípa àṣà àwùjọ tó ti ń kọrin nítorí pé ìpohùn ìbílẹ̀ èyí tí orin jẹ́ ọ̀ kan pàtàkì lára wọn dà gẹ́gẹ́ bí àwògbè tàbí díńgí tí a fi ń ríran rí àwùjọ. Ìlò-èdè tó jinná kò sì ṣe é fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn kí àgbékalẹ̀ orin wọ̀nyẹn lè rídìí jòkó dáadáa kí wọ́n sì lè wu etí í gbọ́. Nínú iṣẹ́ yìí, a ṣe àgbéyẹ̀wò àtí àtúpalẹ̀ díẹ̀ lára àwọn ọnà-èdè tó ṣúyọ nínú àṣàyàn orin ìbílẹ̀ Yorùbá Ìlọrin bíi dàdàkúàdà, bàlúù, wákà, kèǹgbè, sẹnwẹlẹ, kàkàkí/bẹ̀ ǹbẹ́ , Orin ọlọ́ mọ-ọba Ìlọrin,orin agbè àti àwọn mìíràn. Lára àwọn ọnà-èdè tí a gbéyẹ̀ wò ni àwítúnwí, àfiwé, ìjẹyọ ẹ̀ ka-èdè, àyálò-èdè àti ipa ‘Creole’ nínú orin ìbílẹ̀ Ìlọrin. Iṣẹ́ yìí ṣàfihàn pé iṣẹ́ ọpọlọ tó jinná ni orin kíkọ àti pé àwọn ọnà-èdè tó máa ń ṣodo sínú wọn lóríṣiríṣi ní iṣẹ́ tí kálukú wọn ń jẹ́ láti túdìí òkodoro nípa àṣà, ìṣe àti èdè àwùjọ tí onírúurú àwọn orin náà ti ń jáde
- ItemIfiwadiisotumo Iyanrofere Inu Oriki Orile Awon Ilu Ajorukomo-Ifon(2020) Hakeem OlawalePhilosophy of Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ and Nation Building
- ItemPhilosophy of Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ and Nation Building202(2024) Hakeem OlawaleIt is noteworthy that Late Chief Jeremiah Oyèníyì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ is one of the foremost Elder Statesman whose philosophy of life and actions contributed immensely to the development of the country, Nigeria. Despite his demise, his contributions in the history of Nigeria will forever remain commendable because of the positive impacts of his visionary, developmental political philosophy and selfless service to humanity in his social, educational, family, professional and political life. This paper explores multifarious aspects of Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀’s contributions towards the attainment of Nigeria’s independence ; his philosophy of Free Education in the Western Region; his economic policy for the Government; Political life and many others. The paper concludes that if Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀’s developmental and selfless philosophy of life is carefully explored, immitated and practiced, most especially by the political class of nowadays, our dear country will achieve greatness and be freed from financial reckless and embezzlement of the highest order the country is presently battling with.
- ItemWomen in Obasá’s Poetry(2021) Ayoola Oladunnke Aransi; Hakeem OlawaleObasá’s creativity cuts across virtually all aspects of Yorùbá socio-cultural ̣ settings and his works have attracted the attention of various scholars. It is evident that his poems are laden with topical issues that are of national interest. Most of his works, as described by previous scholars, are based on his love for and interest in Yorùbá language, social values, language, style, cultural practices, and the recovery endangered Yoruba oral art (Babalolá 1971, ̣ 1973; Olábimtán 1974a, 1974b; Ògúnsínà 1980; O ̣ látúnji 1982; Akínye ̣ mí 1987, ̣ 1991, 2017; and Nnodim 2006). Tis essay focuses on the representation of women in Obas ̣ á’s poetry, a topic that has not been given adequate attention. ̣ The essay attempts a close reading of Obas ̣ á’s poems within the Feminism and ̣ womanism theoretical frameworks. The research reveals that the representation of women in the poetry of Obasa did not go beyond the stereotypical and derogatory portrayal of women among the Yoruba.